Akure Nile
Akure Nile a song by King Sunny Ade on Foxsoundi — Free Music, Smart Streaming for Everyone
Akure Nile Lyrics
[00:11.10] Akure n'ile to l'oye mekun
[00:17.57] Omo bi d'ale m'ogun erun pa ni
[00:23.76] Akure l'omi meji, won pe ejeji ala
[00:30.27] Ala sebire bire, ala d'omi ebo
[00:39.77] Akure n'ile to l'oye mekun
[00:44.03] Akure n'ile to l'oye mekun
[00:49.38]
[01:09.21] N'ile ni Barrister Lawyer Faloye mi
[01:15.33] International Barrister
[01:19.41] Awon Lawyer r'aja k'aye
[01:21.02] Ajanaku ti m'igbo kijikijikiji
[01:26.03] Eda to ba l'ejo, to ba fe gba lawyer
[01:29.84] Ko lo ri Faloye mi
[01:38.34] Eda to ba ni case, to ba fe gba lawyer
[01:41.71] Ko lo ri Faloye mi
[01:44.46] Barister Lawyer rere
[01:46.68] Ako n'iwaju adajo
[01:49.06] A s'ejo e fun e leto leto se o n gbo
[01:53.39] N'ipari ejo wan a da e lare o
[01:58.87] Barrister Lawyer l'awa n fe
[02:01.35] Koja l'eti ri, wan da e lare o
[02:10.78] Ni gelele ma ba wan debe o jare
[02:14.44] Akure n'ile to l'oye mekun o
[02:19.22] N'ile Iasaac Babalola oko Florence
[02:22.42] Akure n'ile to l'oye mekun o
[02:26.98] Babalola, baba Olusegun o omo ni
[02:30.77] Akure n'ile to l'oye mekun o
[02:34.95] Bank Manager, Babalola mi o ti wa ni
[02:38.67] Akure n'ile to l'oye mekun o
[02:44.65]

From the album: Sunny Ade and His Green Spot Band, Vol. 4
-
Mr. Adenaike (Olulu) by King Sunny Ade , His Green Spots Band , -
John Ali by King Sunny Ade , His Green Spot Band , -
Egbe Board by King Sunny Ade , His Green Spot Band , -
Chief Lekan Salami by King Sunny Ade , His Green Spot Band , -
Prince Adesanya by King Sunny Ade , His Green Spot Band , -
A Ye Wa by King Sunny Ade , His Green Spot Band , -
Akure Nile by King Sunny Ade , His Green Spot Band , -
Major General Adebaye by King Sunny Ade , His Green Spot Band , -
Akanbi Ogun by King Sunny Ade , His Green Spot Band , -
Constant Star by King Sunny Ade , His Green Spot Band ,