Apala Fusion

Apala Fusion a song by Bella Shmurda on Foxsoundi — Free Music, Smart Streaming for Everyone

Apala Fusion by Bella Shmurda

Apala Fusion Lyrics

[00:02.13] (We no be Baba Sálá)
[00:04.29] (Ẹ pè wá l'ọmọ Haruna Ishola)
[00:06.66] (Ònilu mi á lu'lu, á dun gbi-gbim gbi-gbim)
[00:09.10] (We no be motor t'òmá n dun pim-pim-pim)
[00:11.75] (Ẹ jẹ á j'áyè yi, no shaking)
[00:14.20] (Áriwò kọ ni music)
[00:16.68] (Yo Dibs)
[00:17.49] (Ẹni bá lè jò, kò má-má mi kọ)
[00:19.19] (Ilu wá ò lè, álujò wá ò lè)
[00:22.70] (Kò má-má mi kọ)
[00:24.53] (Ilu wá ò lè, álujò wá ò lè)
[00:26.97] I keep it hundred
[00:29.86] I no like f'áyáwọ, I no like f'áyágbè, wọn bẹh
[00:34.66] Ehn, I no dey take nonsense
[00:39.82] I just like to dey shame, I just like to dey go, who stress me? I'm stressed
[00:47.05] I'm getting everything wey I desire
[00:49.63] All of my pain ni mò fi s'árá
[00:52.18] I no far from God, ni mò ṣe n dárá
[00:54.82] If I call you G, you be my brother (aya)
[00:57.46] Òri mi, má jẹn m'òṣi
[00:59.48] Ẹlẹdá mi, má jẹn t'òṣi
[01:02.04] My pikin no go far from money
[01:04.60] Eko no be London, my G
[01:06.86] Òyá, f'áyá gbè, f'áyá kò
[01:09.66] Ṣè kin pọn mi si, ṣè kin dá mi si (ayaya, ya-ya-ya)
[01:12.81] Òyá, kò, bẹrẹ kò (kò-kò)
[01:14.88] Bámi pọn mi si, ṣè kin dá mi si
[01:17.37] Mò yá bẹrẹ kò, bẹrẹ kò, ayy
[01:19.69] (Má gbá mi, má rò mi kiri)
[01:22.21] Say, I no be wanted, hundred
[01:25.61] I keep it hundred
[01:26.92] Busybody, ẹ jẹkin j'áyè
[01:29.69] Busybody, ẹ jẹkin s'áyè miò
[01:31.97] Ọmọtena jọọr, make I s'áyè
[01:34.53] Ọmọtena jọọr, make I s'áyè miò, oh-oh
[01:37.54] Kò ṣ'ẹni tò l'ẹmi mèji (ayy-ayy)
[01:39.25] T'èmi yè mi (oh-oh), I'm not lazy (ayy-ah, Ogunlesi)
[01:42.71] Ah, kò s'Ọlọhun mèji (kò s'Ọlọhun mèji)
[01:44.11] The ọtá many, pẹlu agency
[01:46.85] I keep it hundred
[01:49.80] I no like f'áyáwọ, I no like f'áyágbè, wọn bẹh
[01:55.54] (Ayy, Bella pass Shmurda)
[01:56.82] Ehn, I no dey take nonsense (locate)
[01:59.37] I just like to dey shame, I just like to dey go, wan stress, ṣ'on bẹh (wanted, many lie)
[02:06.91] I'm getting everything wey I desire
[02:09.44] All of my pain ni mò fi s'árá
[02:11.72] I no far from God, ni mò ṣe n dárá
[02:14.43] If I call you G, you be my brother
[02:17.11] Òri mi, má jẹn m'òṣi
[02:19.45] Ẹlẹdá mi, má jẹn t'òṣi
[02:21.99] My pikin no go far from money
[02:24.50] Eko no be London, my G
[02:26.88] Òyá, f'áyá gbè (my G, Eko no be London, my G)
[02:28.59] (We no be Baba Sálá)
[02:29.66] (Ẹ pè wá l'ọmọ Haruna Ishola)
[02:31.54] (Ònilu mi á lu'lu, á dun gbi-gbim gbi-gbim)
[02:33.99] (We no be motor t'òmá n dun pim-pim-pim)
[02:36.64] (Ẹ jẹ á j'áyè yi, no shaking)
[02:38.92] (Áriwò kọ ni music)
[02:41.39] (Ẹni bá lè jò, kò má-má mi kọ)
[02:44.35] (Ilu wá ò lè, álujò wá ò lè)
[02:47.62] (Kò má-má mi kọ)
[02:49.43] (Ilu wá ò lè, álujò wá ò lè)
[02:53.05]

From the album: Sanity