Ogbo

Ogbo a song by Ibrahim Maalouf on Foxsoundi — Free Music, Smart Streaming for Everyone

Ogbo by Ibrahim Maalouf

Ogbo Lyrics

[00:00.30] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh
[00:04.69] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
[00:09.13] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh, Oh, Oh
[00:13.77] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
[00:18.11] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh
[00:22.87] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
[00:27.28] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh, Oh, Oh
[00:31.92] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
[00:36.37] Ọmọ Dafidi, léni ti o ba djè Oba
[00:38.40] Itẹ rẹ o monlè kpélou wura
[00:40.76] Oti wa ni shọ lowo Kiniun méji
[00:42.65] Kiniun meji ti ko jéra o
[00:44.76] N'tori agbara won foun yin l'okan bale
[00:47.38] Kiniun meji ti ko jéra o
[00:49.67] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
[00:54.75] Shugbọn ma gbagbé l'ayé, kpé ojo buruku kan owa
[00:58.97] Igbati won ji janu oruka rè
[01:03.88] Ànjọnú Sakhar lo fọ agbara rè
[01:08.38] Ànjọnú Sakhar lo dji oro rè
[01:12.64] Awon éyé ijosin
[01:15.54] Awon éjé korira
[01:17.39] Awon éyé ijosin
[01:21.96] Awon éjé korira
[01:23.73] Asho ti awon olowo
[01:26.37] Kpelou asho ti awon talaka mawo lo si boji
[01:31.03] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh
[01:35.66] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
[01:40.01] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh, Oh, Oh
[01:44.48] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
[01:49.04] Ọmọ Dafidi, léni ti o ba djè Oba
[01:51.46] Tabili rè nin smaragdu
[01:53.27] On simi lori ẹssẹ oniyèbiyè mẹrin
[01:55.51] Kiniun meji ti ko jéra o
[01:57.69] To fun yin ni agbara, okanbalé
[02:00.23] Kiniun meji ti ko jéra o
[02:02.22] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
[02:07.77] Shugbọn ma gbagbé l'ayé, kpé ojo buruku kan owa
[02:11.63] Igbati won ji janu oruka rè
[02:16.33] Ànjọnú Sakhar da yin kpada bi talaka
[02:20.64] Ànjọnú Sakhar da yin kpada bi alagbé
[02:24.53] Awon éyé ijosin
[02:27.69] Awon éjé korira
[02:30.10] Awon éyé ijosin
[02:34.39] Awon éjé korira
[02:36.77] Asho ti awon olowo
[02:39.06] Kpelou asho ti awon talaka mawo lo si boji
[02:43.44] Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh
[02:48.15] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
[02:52.54] Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh,
[02:57.92] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
[03:01.57] Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh
[03:06.28] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba
[03:10.61] Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh, Oh, Oh, Oh
[03:15.05] Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Oh
[03:19.11]

From the album: Queen of Sheba